39 Nígbà tí Baali Hanani ọmọ Akibori kú, Hadadi gorí oyè, orúkọ ìlú tirẹ̀ ni Pau, orúkọ aya rẹ̀ ni Mehetabeli, ọmọ Matiredi, ọmọbinrin Mesahabu.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 36
Wo Jẹnẹsisi 36:39 ni o tọ