Jẹnẹsisi 37:13 BM

13 Israẹli bá pe Josẹfu, ó ní, “Ǹjẹ́ Ṣekemu kọ́ ni àwọn arakunrin rẹ da ẹran lọ? Wò ó, wá kí n rán ọ sí wọn.” Josẹfu bá dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:13 ni o tọ