Jẹnẹsisi 37:29 BM

29 Nígbà tí Reubẹni pada dé ibi kànga gbígbẹ tí wọ́n ju Josẹfu sí, tí ó rí i pé kò sí níbẹ̀ mọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya láti fi ìbànújẹ́ rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:29 ni o tọ