Jẹnẹsisi 38:13 BM

13 Àwọn kan lọ sọ fún Tamari pé baba ọkọ rẹ̀ ń lọ sí Timna láti rẹ́ irun aguntan rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 38

Wo Jẹnẹsisi 38:13 ni o tọ