Jẹnẹsisi 38:18 BM

18 Juda bá bèèrè pé kí ni ó fẹ́ kí òun fi dógò.Ó dá a lóhùn, ó ní, “Èdìdì rẹ pẹlu okùn rẹ, ati ọ̀pá tí ó wà ní ọwọ́ rẹ.” Juda bá kó wọn fún un, ó sì bá a lòpọ̀, Tamari sì lóyún.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 38

Wo Jẹnẹsisi 38:18 ni o tọ