Jẹnẹsisi 38:26 BM

26 Juda yẹ̀ wọ́n wò, ó sì mọ̀ wọ́n, ó ní, “O ṣe olóòótọ́ jù mí lọ, èmi ni mo jẹ̀bi nítorí pé n kò ṣú ọ lópó fún Ṣela, ọmọ mi.” Kò sì bá a lòpọ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 38

Wo Jẹnẹsisi 38:26 ni o tọ