Jẹnẹsisi 38:5 BM

5 Ó tún lóyún mìíràn, ó tún bí ọkunrin bákan náà, ó bá sọ ọmọ náà ní Ṣela. Ìlú Kẹsibu ni ó wà nígbà tí ó bí ọmọ náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 38

Wo Jẹnẹsisi 38:5 ni o tọ