10 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé lojoojumọ ni ó ń rọ Josẹfu, sibẹsibẹ, Josẹfu kò gbà láti bá a lòpọ̀, tabi láti wà pẹlu rẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39
Wo Jẹnẹsisi 39:10 ni o tọ