Jẹnẹsisi 39:12 BM

12 Obinrin yìí so mọ́ ọn lẹ́wù, ó ní, “Wá bá mi lòpọ̀.” Ṣugbọn Josẹfu bọ́rí kúrò ninu ẹ̀wù rẹ̀, ó sá jáde kúrò ninu ilé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:12 ni o tọ