Jẹnẹsisi 39:14 BM

14 ó pe àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ninu ilé rẹ̀, ó sọ fún wọn, ó ní, “Ẹ wo nǹkan, ọkọ mi ni ó mú Heberu yìí wá láti wá fi ẹ̀gbin lọ̀ wá. Ó wọlé wá bá mi láti bá mi lòpọ̀, ni mo bá pariwo.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:14 ni o tọ