Jẹnẹsisi 39:21 BM

21 Ṣugbọn OLUWA wà pẹlu Josẹfu, ó sì fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kìí yẹ̀ hàn sí i, ó jẹ́ kí ó bá ojurere alabojuto ọgbà ẹ̀wọ̀n náà pàdé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:21 ni o tọ