Jẹnẹsisi 4:12 BM

12 Láti òní lọ, nígbà tí o bá dá oko, ilẹ̀ kò ní fi gbogbo agbára rẹ̀ so èso fún ọ mọ́, ìsáǹsá ati alárìnká ni o óo sì jẹ́ lórí ilẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4

Wo Jẹnẹsisi 4:12 ni o tọ