Jẹnẹsisi 4:15 BM

15 Ṣugbọn OLUWA dáhùn, ó ní, “Rárá o! ẹnikẹ́ni tí ó bá pa Kaini, a óo gbẹ̀san lára rẹ̀ nígbà meje.” Nítorí náà OLUWA fi àmì sí ara Kaini kí ẹnikẹ́ni tí ó bá rí i má baà pa á.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4

Wo Jẹnẹsisi 4:15 ni o tọ