22 Sila bí Tubali Kaini. Tubali Kaini yìí ni baba ńlá gbogbo àwọn alágbẹ̀dẹ tí ń rọ ohun èlò irin, ati idẹ. Arabinrin Tubali Kaini ni Naama.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4
Wo Jẹnẹsisi 4:22 ni o tọ