Jẹnẹsisi 4:4 BM

4 Abeli náà mú àkọ́bí ọ̀kan ninu àwọn aguntan rẹ̀, ó pa á, ó sì fi ibi tí ó lọ́ràá, tí ó dára jùlọ lára rẹ̀ rúbọ sí OLUWA. Inú OLUWA dùn sí Abeli, ó sì gba ẹbọ rẹ̀,

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4

Wo Jẹnẹsisi 4:4 ni o tọ