9 OLUWA bá pe Kaini, ó bi í pé, “Níbo ni Abeli, àbúrò rẹ wà?” Ó dáhùn, ó ní, “N kò mọ̀. Ṣé èmi wá jẹ́ bí olùṣọ́ àbúrò mi ni?”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4
Wo Jẹnẹsisi 4:9 ni o tọ