12 Josẹfu bá sọ fún un pé, “Ìtumọ̀ rẹ̀ nìyí: àwọn ẹ̀ka mẹta tí o rí dúró fún ọjọ́ mẹta.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40
Wo Jẹnẹsisi 40:12 ni o tọ