Jẹnẹsisi 40:14 BM

14 Ṣugbọn ṣá o, ranti mi nígbà tí ó bá dára fún ọ, jọ̀wọ́, ṣe mí lóore kan, ròyìn mi fún Farao, kí Farao sì yọ mí kúrò ninu àhámọ́ yìí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40

Wo Jẹnẹsisi 40:14 ni o tọ