Jẹnẹsisi 40:20 BM

20 Ní ọjọ́ kẹta tíí ṣe ọjọ́ ìbí Farao, ọba se àsè ńlá fún gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀, ó sì mú agbọ́tí rẹ̀ ati alásè rẹ̀ jáde sí ààrin àwọn iranṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40

Wo Jẹnẹsisi 40:20 ni o tọ