16 Josẹfu dá Farao lóhùn, ó ní, “Kò sí ní ìkáwọ́ mi, Ọlọrun ni yóo fún kabiyesi ní ìdáhùn rere.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41
Wo Jẹnẹsisi 41:16 ni o tọ