Jẹnẹsisi 41:21 BM

21 Nígbà tí wọ́n gbé wọn mì tán, eniyan kò lè mọ̀ rárá pé wọ́n jẹ ohunkohun, nítorí pé wọ́n tún rù hangangan bákan náà ni. Mo bá tají.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:21 ni o tọ