Jẹnẹsisi 41:34 BM

34 Kí kabiyesi yan àwọn alabojuto ní ilẹ̀ náà kí wọ́n kó ìdámárùn-ún ìkórè ilẹ̀ Ijipti jọ láàrin ọdún meje tí ọ̀pọ̀ oúnjẹ yóo fi wà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:34 ni o tọ