Jẹnẹsisi 41:36 BM

36 Oúnjẹ yìí ni àwọn eniyan yóo máa jẹ láàrin ọdún meje tí ìyàn yóo mú ní ilẹ̀ Ijipti, kí ilẹ̀ náà má baà parun ní àkókò ìyàn náà.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:36 ni o tọ