Jẹnẹsisi 41:4 BM

4 Àwọn meje tí wọ́n rù hangangan náà ki àwọn meje tí wọ́n sanra rọ̀pọ̀tọ̀ rọ̀pọ̀tọ̀ mọ́lẹ̀, wọ́n sì gbé wọn mì, Farao bá tají.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:4 ni o tọ