Jẹnẹsisi 41:52 BM

52 Ó sọ ọmọ keji ní Efuraimu, ó ní, “Ọlọrun ti mú mi bí sí i ní ilẹ̀ tí mo ti rí ìpọ́njú.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:52 ni o tọ