Jẹnẹsisi 41:7 BM

7 Àwọn ṣiiri ọkà tínínrín meje náà gbé àwọn meje tí wọ́n yọmọ mì. Farao bá tún tají, ó sì tún rí i pé àlá ni òun ń lá.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:7 ni o tọ