Jẹnẹsisi 42:18 BM

18 Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹta, Josẹfu wí fún wọn pé, “Mo bẹ̀rù Ọlọrun, nítorí náà, bí ẹ bá ṣe ohun tí n óo sọ fun yín yìí, n óo dá ẹ̀mí yín sí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:18 ni o tọ