Jẹnẹsisi 42:22 BM

22 Reubẹni bá dá wọn lóhùn, ó ní, “Mo sọ fun yín àbí n kò sọ, pé kí ẹ má fi ohunkohun ṣe ọmọ náà? Ṣugbọn ẹ kọ̀, ẹ kò gbọ́, òun nìyí nisinsinyii, ẹ̀san ni ó dé yìí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:22 ni o tọ