24 Josẹfu bá kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó lọ sọkún, ó tún pada wá láti bá wọn sọ̀rọ̀. Ó mú Simeoni láàrin wọn, ó dè é lókùn.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42
Wo Jẹnẹsisi 42:24 ni o tọ