Jẹnẹsisi 42:27 BM

27 Nígbà tí wọ́n dé ibi tí wọn yóo sùn lálẹ́ ọjọ́ náà, ọ̀kan ninu wọn tú àpò rẹ̀ láti fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ní oúnjẹ, ó bá rí owó rẹ̀ tí wọ́n dì sí ẹnu àpò rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:27 ni o tọ