Jẹnẹsisi 42:35 BM

35 Bí wọ́n ti tú àpò wọn, olukuluku bá owó rẹ̀ lẹ́nu àpò rẹ̀. Nígbà tí àwọn ati baba wọn rí èyí, àyà wọn já.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:35 ni o tọ