37 Reubẹni bá wí fún baba rẹ̀ pé, “Pa àwọn ọmọ mi mejeeji, bí n kò bá mú Bẹnjamini pada wá fún ọ. Fi lé mi lọ́wọ́, n óo sì mú un pada wá fún ọ.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42
Wo Jẹnẹsisi 42:37 ni o tọ