Jẹnẹsisi 42:4 BM

4 Ṣugbọn Jakọbu kò jẹ́ kí Bẹnjamini, arakunrin Josẹfu bá àwọn arakunrin rẹ̀ lọ, nítorí ẹ̀rù ń bà á kí nǹkankan má tún lọ ṣẹlẹ̀ sí òun náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:4 ni o tọ