Jẹnẹsisi 42:6 BM

6 Ní gbogbo àkókò yìí, Josẹfu ni gomina ilẹ̀ Ijipti, òun ni ó ń ta ọkà fún àwọn eniyan láti gbogbo orílẹ̀-èdè. Nígbà tí àwọn arakunrin rẹ̀ dé, wọ́n kí i, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:6 ni o tọ