Jẹnẹsisi 43:12 BM

12 Ìlọ́po meji owó ọjà tí ẹ óo rà ni kí ẹ mú lọ́wọ́, ẹ mú owó tí ó wà lẹ́nu àpò yín níjelòó lọ́wọ́ pẹlu, bóyá wọ́n gbàgbé ni.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43

Wo Jẹnẹsisi 43:12 ni o tọ