2 Nígbà tí wọ́n jẹ ọkà tí wọ́n rà ní Ijipti tán, baba wọn pè wọ́n, ó ní, “Ẹ tún wá lọ ra oúnjẹ díẹ̀ sí i.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43
Wo Jẹnẹsisi 43:2 ni o tọ