Jẹnẹsisi 43:5 BM

5 ṣugbọn bí o kò bá jẹ́ kí ó bá wa lọ, a kò ní lọ, nítorí pé ọkunrin náà tẹnumọ́ ọn fún wa pé a kò ní fi ojú kan òun láìjẹ́ pé arakunrin wa bá wa wá.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43

Wo Jẹnẹsisi 43:5 ni o tọ