Jẹnẹsisi 43:8 BM

8 Juda bá sọ fún Israẹli, ó ní, “Fa ọmọ náà lé mi lọ́wọ́, a óo sì lọ kí á lè wà láàyè, kí ebi má baà pa ẹnikẹ́ni kú ninu wa, ati àwọn ọmọ wa kéékèèké.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43

Wo Jẹnẹsisi 43:8 ni o tọ