Jẹnẹsisi 44:10 BM

10 Ó dá wọn lóhùn, ó ní, “Bí ẹ ti wí gan-an ni yóo rí. Ọwọ́ ẹni tí a bá ti bá a ni yóo di ẹrú mi, kò sí ohun tí ó kan ẹ̀yin yòókù rárá.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:10 ni o tọ