Jẹnẹsisi 44:22 BM

22 A sì sọ fún ọ pé, ‘Ọmọ náà kò lè fi baba rẹ̀ sílẹ̀, nítorí pé bí ó bá fi baba rẹ̀ sílẹ̀, baba rẹ̀ yóo kú.’

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:22 ni o tọ