Jẹnẹsisi 44:32 BM

32 Èmi ni mo dúró fún ọmọdekunrin náà lọ́dọ̀ baba wa, mo wí fún un pé, ‘Bí n kò bá mú ọmọ yìí pada, ẹ̀bi rẹ̀ yóo wà lórí mi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi.’

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:32 ni o tọ