Jẹnẹsisi 45:16 BM

16 Nígbà tí gbogbo ìdílé Farao gbọ́ pé àwọn arakunrin Josẹfu dé, inú Farao ati àwọn iranṣẹ rẹ̀ dùn pupọ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 45

Wo Jẹnẹsisi 45:16 ni o tọ