Jẹnẹsisi 45:19 BM

19 Ó ní kí Josẹfu pàṣẹ fún wọn pẹlu kí wọ́n kó kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin láti ilẹ̀ Ijipti, láti fi kó àwọn ọmọde ati àwọn obinrin, kí baba wọn náà sì máa bá wọn bọ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 45

Wo Jẹnẹsisi 45:19 ni o tọ