Jẹnẹsisi 45:8 BM

8 Nítorí náà, kì í ṣe ẹ̀yin ni ẹ gbé mi dé ìhín, Ọlọrun ni, ó sì ti fi mí ṣe baba fún Farao, ati oluwa ninu gbogbo ilé rẹ̀ ati alákòóso gbogbo ilẹ̀ Ijipti.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 45

Wo Jẹnẹsisi 45:8 ni o tọ