Jẹnẹsisi 46:12 BM

12 Àwọn ọmọ ti Juda ni: Eri, Onani, Ṣela, Peresi, ati Sera, (ṣugbọn, Eri ati Onani ti kú ní ilẹ̀ Kenaani) àwọn ọmọ ti Peresi ni Hesironi ati Hamuli.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:12 ni o tọ