Jẹnẹsisi 46:15 BM

15 (Àwọn ni ọmọ tí Lea bí fún Jakọbu ní Padani-aramu ati Dina, ọmọ rẹ̀ obinrin.) Gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ lọkunrin ati lobinrin jẹ́ mẹtalelọgbọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:15 ni o tọ