Jẹnẹsisi 46:25 BM

25 (Àwọn ọmọ tí Biliha bí fún Jakọbu ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ jẹ́ meje), Biliha ni iranṣẹbinrin tí Labani fún Rakẹli, ọmọ rẹ̀ obinrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:25 ni o tọ