Jẹnẹsisi 46:27 BM

27 Àwọn ọmọ tí Josẹfu bí ní Ijipti jẹ́ meji. Gbogbo eniyan tí ó ti ìdílé Jakọbu jáde lọ sí Ijipti patapata wá jẹ́ aadọrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:27 ni o tọ