Jẹnẹsisi 47:13 BM

13 Ìyàn náà mú tóbẹ́ẹ̀ tí ìdààmú bá gbogbo ilẹ̀ Ijipti ati ilẹ̀ Kenaani nítorí pé kò sí oúnjẹ rárá ní ilẹ̀ Kenaani.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47

Wo Jẹnẹsisi 47:13 ni o tọ