16 Josẹfu bá dá wọn lóhùn pé, “Bí kò bá sí owó lọ́wọ́ yín mọ́, ẹ kó àwọn ẹran ọ̀sìn yín wá, n óo sì fun yín ní oúnjẹ dípò wọn.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47
Wo Jẹnẹsisi 47:16 ni o tọ